“Ga sίi fúnralárarẹ láìfagbáraṣe”

tó lágbára jùl láti ga sίi láìfagbárae!

 

Fojú inú wò pe ó le sàkóso ayé ati gíga re. Báwoni yó ti rί kóo wo jígí tί osὶ rί eni gíga tó wuni, osὶ mộ pé o gbḙgḙjḙ. Fi ìṣẹ’jú kan ro bí àwọn ộrệ àti ará o ti fèsì nígbàtí wộn obá rìn wọnú yàrá tί ìfarahàn ré ga, dára, tóὸ sὶ kún fún ìdánilójú titun. Àwọn oníbàárà wa ὸnί láti fojú inú wòó, Super-Growth ti rànwọnlộwộ láti gbàṣàkóso àti ga sίi. Kà nípa wọn, kí o rí bí Super-Growth ti yí ayée wọn padà tó si rànwọnlộwộ láti di ẹni tί wọn fẹ.

 

Èhù Áìfagbáraṣe Super-Growth Height Enhancer

Super-Growth Sprey

Super-Growth Spray

 

 Rí ìyọrí-sí níwộnba oṣù díẹ!

 

Ànfàní:

 

 • Láti ga si
 • Láti ní okun-inú si
 • Fún ìmúdára adánidá

 

Nígbogbo agbáyé, àwọn eléré ìje, módẹli, oníbộôlù afọwộ gbà, àwọn oní iṣan ara àti àwọn olúkúlùkú nrà Super-Growth láti ga si àti fún ὶrọrùn ara. Super-Growth ófi kún ìdàgbàsókè nípa fifikún ìwộn HGH rẹ àti nípasẹ ὶtúnṣe àwọn òkérékè ré, ojú òòrùn àti egungun rẹ. Super-Growth Height Booster yoóràn ộ lộwộ láti ga si ní kíákíá àti láti mú ìdúró rẹ dára si.

 

Ìdí ti gíga ộpộ ènìà tàsé ni pé àwọn onί ìmộ sáyệnsὶ ótíì riộnà láti jệ kí ẹṣệ ti múni ga pösi tinú-tinú láìfagbáraṣe. Ẹṣệ ti múni ga ló ṣe pàtàkì jùlọ lati ṣàkóso ìdàgbàsókè egungun rẹ nítorí òn nìkan ló le ṣe ìrúsóké fún òkérékèré tó wa ní ìpệkun egungun rẹ (èyí níí gbé ẹrù iṣê ìdàgbàsókè egungun tí ó nà ró). Ìlò Super-Growth ó ràn ọ lộwộ láti ga si àti láti mú ìdúró rẹ dára si.

 

Super-Growth Height Booster ò léwu, o ní ὶyọrísí, oń ṣiṣệ, o rọrùn, kὸwộn, ó jé ìmọ ộnà àmúṣe titun nínú èhù ti múni ga si, ti awộn ẹgbệ àjùmö ṣiṣệ sàyẹnsὶ tί ṣe ìwádi kíkan kíkan lórí.

 

Kὸ nί:

     Kὸ nί lὸ ìje kankan, kὸ nί lὸ iṣệ abẹ kankan, kὸ nί lὸ abẹrẹ kankan, kὸ nί lὸ nίnà ara kankan, kὸ nί lὸ àwộtệlệ bàtà dídun-ni Kankan.

 

Ilé iṣệ Super-Growth pèsè fún ìlòsí tìgbàyí aláìléwu tί yó ràn ọ lộwộ láti ga si ní kíákíá tί yó si tún jί ìdàgbàsókè egungun àti adánidá ara rẹ. Láarín oṣù kíní, oó bệrệ sί rí ìyípadà, bíi ìmúdára ìdúró rẹ àti àtúnṣe gígasίὶ rẹ.Kà si….Kà ohun tí awộn oníbàárà tó kúnlójúń wí

Mo ga si nί irú ìwộn mệệta (3cm) lêhìn oṣù kan tί mo bệrệ sίnί lò ọjà na. Mi o nί gbà-gbô pé mo le ga si! Ẹ ṣeún.

William Glover, ọjộ orí: 25  Australia         ệrí tókù….

 

Mo tί ń lo láti ìgbệhìn oṣù kárùn ó sίὶ dára. Mo jệ 5’4 ṣùgbộn nίsisìyí mo jệ 5’7 nί giga, mo nírètí pé pệlú Super-Growth màá ga sίi.

Shawn Brown, ọjộ orí: 23 THE USA

 

Mo ga nί ìwộn mệệfà (3 inches) láti ὶgbàtí mo tί ra Super-Growth nί oṣù mẹệjọ sệhìn.Mo ó tίὶ nί gbóíyà bayi rί. Ìtὶyanu ni pé giga dίẹ sίi le mú ènìà nί gbóíyà si.

Darren Wong, ọjộ orí: 20 Singapore

 

Nί bίi oṣù mệệta àti àbộ sệhìn, mo rà ọjà naa wὸ laigbà-gbộ pé yó rànmίlôwô. Síbệ-síbệ nígbàtí mo bệrệ sί lὸó, lệhìn oṣù kan mo ríi pé mo ń ga si. Ki ń tó bệrệ sί nί lὸ mo jệ 5″9½(~1.76m), lệhìn oṣù mệệta mo jé 5″11½(1.82m), nítorínáà modúpệ, èmi ó  tile gbà-gbộ pé yó ṣίṣệ dáádáá. Ilé-iṣệ Super-Growth mo dupé, ệti jé kί ayé mί yàtộ pátápátá, Nì isin yí awộn ènìà ma ń wὸ mί dáádáá nί gbogbo ìbì tί mo bá lọ, ó  si dára bί awộn ènìà tί ń ṣe akίyèsí mi yàtộ sί tệlệ. Lệệkan sίi modúpệ.

Justin Wood, ọjộ orí: 19 , The  USA

 

ÌWISUN  (INFO)

 

SUPER-GROWTH HEIGHT ENHANCER NI AMÚNI GASĺI ADÁNIDÁ TÓ KỘKỘ Nĺ ÀFỘWỘSĺ.

 

N jệ gíga si ṣeéṣe?

 

Gíga si ṣeéṣe! Bί o bá fé ga sίi, o nί ìrệwệsí tàbí ìṣòro ệdùn ọkàn tί ó tanmộ ὶdá-dúró nínú ìdàgbàsókè re, iṣé re, kúkúrú re àti itú-sílè ìdúró, nί wàyí ìdáhùn tί wà fún ọ tóle mú ọ ga si.

 

Sé o mộ pé: Ole ṣàkóso ìdàgbàsókè re láìfiyèsí ohun abínibí àti ohun ti awộn ènìà ńwί.

 

S.G Inc. Tí ṣe éhù tί ó le múni gasίi akộkộ èyí tí ó níyộrísí.

“Super-Growth height enhancer ni akộkộ èyí tí ó níyộrísí láti rànnίlôwô àti gasίi láìfagbáraṣe àti láti fikún ìdàgbàsókè adánidá re”. Super-Growth height enhancer tί fihàn nínú idánwò pé ó níyộrísí láti jệkί àgbàlagbà gasίi lệhìn tί gíga eni tί parí.

 

Bi ὶgasi ènìà ṣe ńṣệlệ?

 

Bί ara àwa ènìà ṣe ńga si jé ệrọ tί kòpè. Aní orίṣirίṣί ètò tί ń ṣàkóso ara wa. Ộkan lárawộn jé “ètò  ẹṣệ” àbí ètò Endocrine. Ẹṣệ kékeré tίί jé pituitary pín sί méjì: tiwájú àti tệhìn.Ti iwájú nìṣe dédé iṣệ thyroid, adrenals àti ètò ìbí-sí. Ti ệhìn nṣe ẹṣệ tί múni ga sίi (Growth Hormone), ti siìṣe ìdàgbàsókè egungun àti ệyà ara, ó sὶ nípa nínú bί ara ṣe ńṣàkóso onjẹ tí ńfún ni lókùn.

 

Growth hormone (GH) àbí somattoropin (STH) jé ẹṣệ tί rú ìdàgbàsókè àti ìbísi ệyà-ara ènìà àti awộn ẹranko. Ó jệ 191-amino acid, ónί ệwộnkan ẹṣệ polypeptide tó ṣó-gbôn, ṣabà àti mújade nípa ệyà-ara somatotroph tó wà nínú ẹṣệ pituitary ti iwájú.

Ìṣe GH táa mộ jù náà ni nίnú gίga ènìà, ó sὶ hàn pé rίrú sókèerệ wà nípa okékeréjù, ệrọ méjì. GH tààrà ńrú ìpín àti ílộpộ chondrocytes tί òkérékèré. Wộn wà nί òpin (epiphyses) awộn egungun gίgùn (ápá, ẹsệ, ọmọ-ìka).

 

GH náà ńrú ìbísi bί “insulin growth factor 1” (IGF1), ẹṣệ náà nί ìpilệṣệ proinsulin. Ộdộki nί ệyà-ara tί GH tίń ṣìgbéṣệ àti ίbí pàtàkì fún ìbísi IGF-1. IGF-1 ńjệ kί ệyà-ara orίṣirίsί so, o ṣὶ lérú nί ệbáá náà, èyí fίhàn pé o jé endocrine àti autocrine/paracrine. IGF-1 lé rú osteoblast àti chondrocyte tί so ìdàgbàsókè egungun.

 

Super-Growth ó fikún ìdàgbàsókè rẹ nípa fίfikún ìwộn HGH rẹ àti nípasẹ itunṣe awộn òkérékèré, ojú òòrùn àti egungun rẹ. Super-Growth Height Booster yó ràn ọ lộwộ láti ga sίi ní kíákíá àti láti mú ìdúró rẹ dára si. Láarín oṣù kíní, oó bệrệ sί rí ìyípadà, bíi ìmúdára ìdúró rẹ àti àtúnṣe nίnu gíga rẹ.

 

Iṣệ wa:

 • A pèsè ọjà tól’agbárajù fún àwọn oníbàárà wa.
 • A  fún awộn oníbàárà wa nίdánilójú pé awộn eròjà ṣe gệgệ báa ti sộ.
 • Ań ṣiṣệ pệlú ótítô inú l’àìṣèrú.
 • A fún ikộkan oníbàárà wa nί ìtộjú àti ìfojúsí tó bá ìní wộn.
 • A pèsè àpèwò ộfệ láti inú ìrírí wa.
 • A gberu àtiṣệ ὶsèdásílệ èhù tί kòsί nί ίbòmíràn.
 • A ṣe àkóso ìkójộ ệkùn lórí èhù wa, pệlú àṣàrò áti àfiwé onírúurú èhù.

S-G Inc. tayộ. A ṣe àjùmộ pệlú awộn oníbàárà wa láti ṣe ὶdásílệ èhù tó wúlò, tólókù nibikíbi nί gbogbo àgbáyé. A tίṣe àṣeyộrí pệlú awộn oníbàárà níbí tó jé kί wộn lérè,wúlò nί ibiṣệ débi pé a ti so lộnà ọgộrun mệệfà (600%) nίnu ọdún mệệta.SG Inc. yàá sộtộ láti gbé èhù àrà titun jade fún àwọn oníbàárà wa.

 

À tiṣe àṣejèrè l’ọrộ-ajé òní; ènὶà ní-lò èhù tó lagbára áti ṣiṣệ nídàájú tó sὶ le ṣệyàtộ layé ẹnití ńlo. Èyí tumộsί pé kὶίṣe ὶpèsè èhù alàìlábàwọn tó dára jùlọ nìkan, ṣùgbộn èyί tónί iye áti ìwộn totộsí fún ohun tί àń ńlépa.

 

Àkópộ Ìríríwa pệlú ìdánwò tó dájú rànwálộwộ láti ṣ’ákòótán èhù t’ónί èrè gίga. L’áìṣeyèméjì pàtàkì ὶpèsè àkójộpộ ohun èlò tó níyộrísí yéwá, ó sίὶ tệ àwọn oníbàárà wa lộrùn tί wộn ṣί ń tún ộjà wa ra nίnu òwò abánidù òní.

 

ÌBÉRÈ ÍGBÀGBOGBO (FAQ)

 

A t’iṣe ìwádìí ὶjὶnlệ láti rí awòtán lộnà ìbílệ tί kὶί rànni lộwộ láti ga si nìkan ṣùgbộn óní íyọrísí áti àwọn atộkùn ló ṣákoso rệ.

 

Sé odájú pé oń ṣiṣệ?

 

Super-Growth © Growth Formula ṣe iwúlò, ὶwộn àṣeyộrí rệ ṣὶ ga. Iye ìgbà tί wộn tún ộjà wá bérè ga, ìfihàn pé ó tệ awộn oníbàárà wa lộrùn. Nìdájú, a ti tàjà fún ệgbệgbệrun oníbàárà nί gbogbo orílệ èdè àgbáyé!

 

Àti ὶgbàwo ni èhù yίn ti wà lộjà?

 

A gbé Super-Growth jáde nípa ìwádìí jộjộ, pệlú àṣeyộrí ńlá, fún ó’lé ộdún mệệwá. N’ilé èròjà SG. Inc. oó rί èhù ὶbίlệ tó lágbára gίga fún ὶdàgbàsókè rẹ nίnú ìwộn òògùn kộkan,  t’àgbékalệ  nίpasệ àwọn onί ὶmộ.

 

Nkan pàtó wo ni Super-Growth © ńwòsàn?

 

Super-Growth © tί yege, óní ὶyộrísí, kὸ léwu rárá átipè ó jệ ewé ὶbίlệ tó le mú ara yá gágá, tún ệdộ áti tún dída onjệ ṣe àti ràn ộ lộwộ láti ga si láìsí ìpalára. Pệlú Super-Growth Height Enhancer ole ga si lailéwu àti láìfagbáraṣe nί kíákíá láìsí àpadàwộsí.

 

Ńjé Super-Growth © nί ìfohùnsí FDA?

 

FDA nίṣe àkóso gbogbo ộjà onjệ àti ògùn. Ìgbàtí Super-Growth jệ ègbo igi ó bộ sί abée FDA. A fún yίn nί ìdánilójú pé èyί kὸ dίn agbára èhù náà kù. A ti gba èsì aláìyíhùn padà lộwộ àwọn ẹnití ńlóὸ.

 

Ìgbà wo ló dára jù láti lò Super-Growth © ?

 

Lò Super-Growth © ní ìṣệjú mệệwá sí méjìlá kí o tó sùn.

 

Ộnà wo ló tộ láti ṣabà èhù yí?

 

Ìbì tó dárajùlộ ní ìbì tí ò gbóná (kì ṣe ìbì tótútù), ṣókùnkùn tí ò sí lábệ òrùn tàrà bíi inú pẹpẹ tàbí inú kộlộfín. Kò ní-lò ẹrọ tí ńmú ńkan tutu.

 

Nígbàwo ni àtúnṣe ó yọ?

 

óyàtộ fún ẹni kộkan, ṣùgbộn ộpộlọpộ ènìà ńkộkộrí ìyàtộ nínú ộsệ mệrin, ὸsί le pệ jubệệlộ fún ệlòmíràn. Díệdíệ ní ìyàtộ ó dé. Lìlòó ní dédé fi ígasí hàn, imú dára ìwà àti àsunkún okun-inú. Super-Growth ti ní àṣeyộrí gíga àti ìyộrísí. Wộn tún ộjà wá bérè àti-pé fún ộdún, awộn oníbàárà ńfi ìyìn tó dájú ránṣệ.

 

Fún ígbàwo ní kí ńlò Super-Growth © àti-pé kíni ὶdί?

 

Fún ìyộrísí tóṣe wàrawàra a gbìi nìmöràn pé kóo lo Super-Growth ní dédé. Líloóní dédé ó fi ígasi, imú dára ìwà àti àsunkún okun-inú hàn nínú oṣù kan sí mệệfà (1-6).

 

Ṣe Super-Growth © ní àpadàwộsí èyíkéyìí?

 

Rárá, Super-Growth Height Enhancer © ò ní àpadàwộsí kankan, bí ó ti lộnà ọgộrun (100%) jệ nkan àtilệwá àti ewébệ (egbo igi). Awộn eròjà Super-Growth Height Enhancer © jệ nkan aláìléwu àtipé lákòópộó ṣeé gbà láìsíà padàwộsí.

 

Kíni àlòpê ìgò kan?

 

Ìgò kộkan ṣe dédé oṣù méjì bí ó bá fo ọjộkan láàrín. Ìgò kộkan ní 30ml tàbí ìlò tóṣe dédé oṣù méjì.

 

ṣé ọmọdé lè lo Super-Growth Height Enhancer © láìléwu?

 

Àwọn ọmọdé láti ọdún mệsàn sókè lèlo Super-Growth Height Enhancer ©. A gbίnìmộràn pé kί o jíròrò pệlú oníṣègùn rẹ tàbí àbójútó ìlera rẹ fún ìbérè àti àmộràn nipa tí ὶgasί, ìwúwosί àti ọjộ orí ọmọ rẹ.

 

ṣé àpadàwộsí wáà fún èhù yí?

 

Super-Growth Super-Growth Height Enhancer jệ èhù ὶbίlè àti èhù tó lagbára gíga láìléwu tó sίὶ níyọrísí. Kὸsί àpadàwộsí òdì kankan pệlúèhùyí.

 

ṣé ện rán ọjà sί orílệ èdè mi?

 

Àn ránjàsí gbogbo àgbayé. Ìnú dídùn wa ni nίnί oníbàárà nί gbogbo àgbayé tί a ṣiń ránjàsí gbogbo orílệèdèyí.

 

Báwo ni moṣe le dá èhù náa padà? ṣé mo le ṣé?

 

Nítorí irú èhù yí, àń gba èyí tί wộn tίὶ ṣί tàbí tί ámì ìfìwé ránṣé rè gangan wá nípípé. Bί ọjà re ὸbá sί nί ṣίṣί, o le dápadà fún ìdí èyíkíyìí. Àń gbà ọjà tί wộn bá dápadà láarín ọgbộn ọjộ sί ìgbà to rà. Ó gba iye tί o fi rà pada, láìsí owó tί ó fi ránjà àti ìbáṣòwò tί ìdíyelé àti $5.00 fún owó ígbéṣẹ dίdáapadà.

 

ṣé ìdínwókù fún rίra ộpộ wà?

 

Ó dájú. Àn ṣé ìdínwókù fún ọjà púpộ fún tίtà tàbí fún onírúurú ẹgbệ. Sáà fi ìwé ệrọ olóye (email) ránṣệ sί sales@super-growth.com kί osὶ jệ káà mộ èyí tó wù ộ.

 

Mo fệ tà ọjà yín, ṣé ệ rán ọjà yín sί àwọn oníbàárà mi?

 

Bệệni, anί ètò fίfi ọjà ránṣệ. Jộ pèwá tàrà, jệkí a mo ìbì tί o wà, àti ộnà tί o fé gbà ta ọjà yί.

ÀWỌN ẸRÍ

 

Adúpệ lộwộ ẹnikộkan tó fi àkókò rệ f’ệrí ránṣệ lórí ệrọ olóye (email), inú wa dùn pé e rí ìyộrí-sí pệlú èhù!

 

Mo jệ ẹni ọdún méjìlẹlogún mo sì nί ὶṣὸro pệlú ὶgasίί mi nítorí mo jệ ẹni tó fệràn eré ìje.

Àwọn ènìà nί ὶretí pé óye kίńjé ẹni tó ga tί ósὶ nί ara tó suwộn.

Mo lò orίṣirίṣὶί èhù láti gasίi ṣùgbộn mo fowó ṣófὸ. Nígbàtí mo

rà super-growth fún oṣù mệrin mo sọ fún raà mί

pé èyí ni màá rà gbệhìn. Nítorínáà moń lo super-growth fún oṣù mệrin

láìkọbiara sί ṣùgbộn ὶyanu ló jé fún mί nígbàtí mo kiyèsí pé

mo ga ju ộkan lara awộn ẹgbệ mί ló! Mo kọbiara sί mo sὶ ga sίi pệlú irú ìwộn mệệfà

(3 inches)!!!!!! Mo jệ 5’5 tệlệ wàyío mo jệ 5’8!!! Mo ṣὶ fé ga

sίi!!!! Mo dúpệ lộwộ super-growth!!!!!!!

 

Alexander ,22 years,Czech republic

 

Ẹ nlệ.. Orúkọ mί ni adik láti Malaysia..

Mo kàn fée sọ nípa ìrírí pệlú èhù yίn.. Mo jệ 164.5cm ..Mo jệ ẹni kúkúrú

fiwé mί awộn ọmọ ìyá mi..Mi ὸ nί ὶgboyà.. bệrệ sίnί ṣe ìwádìí nípa

àti gasίi..ộpộlọpộ sọpé kὸṣeéṣe láti gasίi fún ọjộorí mi

..Mo fệ gbàgbé ệ títí tί mo fi rί yίn lórí ệrọ. mo pinnu láti dánwò..mo

rà super-growth ệkún oṣù mệệfà..nί oṣù méjì àkộkộ món ṣe làálàá

nítorítí mi ὸ  rί àtúnṣe..mo bệrệ sί nί gbà-gbộ pé èhù náà o

ṣiṣệ fún mi.. lệhìn oṣù mệệta óṣe mί yàtộ..mo bệrệ sί nί gasίi..Ọlộrun ṣeun

..ẹmú ìlérí yίn ṣe ..ní lộộlộộyi mo ṣé ìwộn mi.. nί ìyàlệnu nìsìsìyí

mo jệ 169cm… ὶyàtộ 5cm..Ẹ ṣeun . Màá mộn lo

èhù yίn títí màá fi ga débi tί mo fệ..lệệkàn sίi mo dúpệ fún ìrírí ộtộ tί mo rί.

 

Adik,Malaysia.

 

 

Ẹ nlệ,

Eléèyí kὶί ṣe ìbérè.

Dípò mo fệ sọ nípa ìyàlệnu àti ànfàní tί mo rί nínú èhù yίn.

Mo ṣệṣệ lo super-growth fún oṣù mệệfà mo sὶ t’irί èso!

Mo gbộdộ sộ pé mo ṣíyèméjì kίn tó bệrệ sί lὸ.

Ànί jệ ẹni ọdún méjìlẹlogún mi ὸ sὶ nírètí pé mo le gasί.

Mo bệrệ sί lo super-growth pệlú 1.85cm l’ago mệệwá àárộ.

Nígbàtí wộn mo fún ìwé ìyộdà ìwộlú tàbí ìjádelọ lệhìn oṣù mệệfà mo jệ 1.92cm l’ago mệệwá àárộ.

Ìyàwó mi sọ pé ìdúró mi dára si.

Ídájú? Mi ὸ rὸ bệệ. Fún gbogbo ὶgbà tί m’orántί mo jệ 1.85cm làárộ!

(Mo ti wộn nί iye ὶgbà tί mo fệ jà ìjàdù)

Wàyí mo nìgbàgbộ nínú èhù yίn mo sὶ ń wo wájú fún ìyộrí-sí!

Ìwù rere.

Lucas

SWEDEN

 

 

Mo jệ 5’5 nígbàtí mo bệrệ sί lo super-growth. Nίsisìyí mo jệ 5’7! Mo ti ga sί n’iwộn 2 inches nί ópộộjù oṣù méjì tί mὸ ńlo Super-Growth! Super-Growth wulệ ńṣiṣệ tinú-tinú láìsí ògùn kíkan kankan. Mo mộ pé màá ga sίi nί ọjộ wájú tί nbá múra sí Super-Growth.

Nítòótộ.

Aloysius Sim Jaladri , ọjộorí: 26  Singapore

 

 

 

 

O ṣeun Super-Growth tó rànmίlộwộ láti ga sίi. Mo ṣệṣệ lo Super-Growth fún oṣù kan mo sὶ ga n’irú ìwộn mệệta . Nὶkan kộ ni mo ga sίi, óti mú gbogbo ànfàní tó lérí ṣẹ.

Edgard Fiorenza, ọjộorí: 21 France

 

 

Mo ju ọgbộn ọdún lọ, nítorínáà mo ṣíyèméjì nίpa Super-Growth, mo sὶ rὸ pé kὸsί ộnà tί mo fi le ga sίi. Síbệ-síbệ lệhὶn oṣù méjὶ tί mo lo super-growth, mo ti rί ìdàgbàsókè nί irú ìwộn bίi méjὶ. Nίsisìyí mo mộ pé ó ńṣiṣệ, ó ṣὶ fún mi n’ίgbệkệlệ láti tệ-síwájú, n’ίmộ pé mo l’erί ìyọrí-sí tó dàra sίi. Super-Growth rọrùn láti lò, níṣọra àti ṣàìní ìrora. Nìrántí ó nί níyọrísí ju awộn ệyà yókù.  Ẹṣé!!

Boris Ivanov, ọjộorí: 35  Moscow, Russia

 

 

Mo ki yin lati New York. ệrί mi nὶί.

Mὸń kộwé yí láti Manhattan, NY. Oníbộôlù afọwộ gbà ni mί fún ilé-ìwé gíga kan. Mo fệ sọ fún gboggbo  ẹnikệni to ngbèrò láti ga sίi pé Super-Growth ńṣiṣệ. Yó ràn ẹnikệni lộwộ láti ga sίi. Ẹșeun fún ìrànlộwộ.

Bill Beckford, ọjộorí: 20  NewYork

 

 

 

Mo jệ ọmọ ọdún mệệtadίnlogún, mo jệ 1.50m nί gίga..bί oṣu méjὶ ti kọjá (làfiyèsí) mo sὶ tί ga sί 1.57m!. Wow! ὶyẹn pộ gan. Kódà ó ya àwọn ộrệ mi lẹnu. Mo ti fệ ga tó àwọn ộrệ mί tó ga jù mi lọ, àwọn òmíràn ti kúrú jù mi lọ. Mi ὸ tίệ tίlệ rὸó pé mo le ga tó bàyí sί.

Catarina Carneiro, ọjộorí: 17 Fortaleza,  Brazilian

 

 

Nkan tó dára jùlọ nípa Super-Growth ni pé ómú àlá mi láti ga sί ṣẹ. Mo ga sί pệlú 3 inches nί oṣu mệệfà. Ó kọ mi l’ệkộ kan: ká fi àlá wa s’ọkàn kásὶ lo àyèkáyè ta bá rί láti mú ṣe.

Ed Barry , ọjộorí : 19  CA, The USA

 

 

 

Ẹ nlệ, Orúkọ mi ni Gulshan, mo wá láti India inú mi sί dùn pệlú èso èhù yί. Mo jệ 5’7 wàyí nínú oṣu mệệta mo ti ga sί pệlú irú ìwộn márùn-ún. Ẹ ṣeun fún ìrànlộwộ yίn, ìdánilóhùn àwọn oníbàárà yίn tayọ. Mo só fún àwọn ộrệ mi nίbí Delhi nípa ọjà wộn sὶń ṣàníyàn àti ra ọjà yίn.

Gulshan K. , ọjộorí : 24  New Delhi, INDIA

 

 

Mo ti ra ọjà yίn nί bíi ọdún mélὸo sệhὶn nígbàtí mo jệ ọmọ ọdún méjὶdίnlógún (mi ὸ ga mộ fún bíi ọdún mệệta sί ὶgbà náà). Àlá mi ni láti jệ módélὶ, ṣùgbộn igasί mi ὸ jệ. Mo tiń lo Super-Growth fún àpapộ oṣù mệệfà mo sὶ ti ga láti 5’3 sί 5’6. Mo ṣệ ńtún sáίtὶ yίn wὸ. Bί mo bá le ga sίi fún bíi irú ìwộn mệệfà, àlá mi yó ṣệ. O ṣeun Super-Grow!!!

Sindhu  M. , ọjộorí : 21  Bangalore, KARNATAKA, INDIA

 

 

Mo ju ọdún méjὶlélógún lọ nítorínáà mo ti kọjáa àkókò èwe ọkùnrin àtipé ìgbàgbộ mi ni pé

mi ὸ nί àyè láti ga mộ. Kίn tó lo super-growth mo jệ 164 inches ṣùgbộn mo ti ga sίi

mo sὶ ti jệ 166 lệhὶn tί mo lo fún oṣù mệrin.awwwwww……..ὶyàlệnu lójệ …….. kodà óya àwọn ộrệ

àti ará mi lệnu.Nkan tó dára jù nὶpa Super-Growth nipé ó mú àlá

mi ṣệ.Oṣé >>>>>super growth.

Qabbo , ọjộorí : 22  Dhaka, Bangladesh


Bàwoni, mo kàn fé sọ pé èhù yί ńṣiṣệ. ọdún mệrindílógún ni mi nίgbàtί mo kộkộ ra super-growth, èso rè ṣe mί nί kàyéfὶ. Mi ὸ ṣὶ le gbàgbộ pé mo ga nί ὶwộn 3.5 inches nί oṣù mệệfà. ìgbàgbộ mi tệlệ nipé tί mo bá fé ga sί mo gbọdộ ṣe iṣệ abẹ tàbi lo ὸgùn ṣùgbộn kὸ rί bệ mộ. lệhὶn ὶgbà tί mo lo super-growth mo jệ 5’4.5, nί oṣù mệệfà sệhὶn mo jệ 5’1. Mo fệràn bί asọ mi ṣe bámimu àti bί àwọn ọkùnrin súnmộ mi. Dájúdájú ayé mi ti rί ὶyίbadà, ọpệ lộwộ super-growth. Mo yìn èhù yί fún ẹnikệni tί kὸ bá nί ὶdánilójú àti tί inú rè ὸ dùn nítorítí kὸ ga: O LE SE ŃKAN NίPARẸ!!! Nidájúdájú màá mộ lo super-growth láti ga sίi àti  láti nί ὶgboyà. O ṣeun super-growth tó yί ayé mi padà.


Ẹ pệlệ Height Growth Plus!

 

Mo kàn fé sọ ẹṣé TÓTÓBI fún èhù ìyanu yί. Mo rίigbà

nί bίi oṣù mệệfà sệhὶn mo sὶ bệrệ sί lὸó lệsệkannáà. Ọkùnrin 5’7 ni mί tệlệtệlệ,

nίsisὶyί láarín oṣù mệệfà mo jệ 5’11.4. Mi ὸ le dúpệ lộwộ

yίn tó àtipe màá yin èhù yί fún ẹnikệni nί ọjộwaju.

Lệkàn sίi ẹṣeun,

Martin / USA


Ẹ nlệ

Àlá mi ṣẹ. Mo ga nίwộn mệệta nί oṣù kan péré.

Ohun ìdánilójú ni.

Mo wá jệệri lórίi sáίtὶ yίn ni.

Mo ra ọjà yίn ó sὶ tệlmilộrùn.

Eṣe gan.


Ẹ pệlệ o,. Moti ga nί ìwộn dίệ láarín oṣù kan….ὶyanu!!! Báwoni mo sele lὸó láti ga dé ibi tί

mo fé láìléwu? Mo fệ ga nί ὶwộn 2

inches. Pelú sé áìyệsệ ni ìdàgbàsókè nidagbasoke náà?

Ẹ ṣeun púpộ.

Sheral/USA


J’ai Ógún ódún ni mί, mo lo ộjà yίn fún oṣù

méjὶ àti àbộ. Mo sὶ ti ga fún bίi irú ìwộn mệệta. Inúmi dùn pệlú èso rè

Ẹṣeun,

France


Ẹ nlệ nίbệhún, mo jệ 5ft1 tệlệ mo sὶ ti gbìyànjú tίtί. mo

ra Super-Growth lórí ebay bί mi ὸ tί mὸ pé enί sáίtὶ yίn.

Mo ra onί oṣù mệệfà ṣùgbộn láti ὶgbàtί mo ti ràá ódábí pé wộn ὸ tàá mộ

lórí ebay.

ṣùgbộn nὶgbàtί mộń wá ίsopộ ni mo ṣe àbápàdé sáίtὶ yίn.

Mo ti jệ 5ft 3 inches – lộwộ Super-Growth nὶkan – mo mộ pé mo le

ga jù báyί lọ.

ṣé ó nίlὸ àwòrán fún èrί yί?

Ìwù rere.

Michael


“…. Mo kàn fé sọ pé mo mọyì  ὶhà tekọ sί àwọn oníbàárà yίn àti fifún ṣộkan ίmelὶ wộn. ὶdùnnú ni láti rί ilé-iṣệ tó báwộn oníbàárà gbìrò lệhὶn tί wộn bá rajà. Ẹmúra sί iṣệ rere yίn!”

CRISTIN, Ireland


” Mo kàn fệ kίệ mộpé mo ti rộjà náà gbà… Ẹṣeun lệkansίi fún ìrànlộwộ yίn!”

Amelia, Germany


“.. Inú mί dùn pệlú èhù náà àti bó ṣe tètè dé jệ kί inú mi dùn.”

Sofia, Singapore


“Inú mί dùn gan pệlú èhù náà àtipé inú mi dùn bóṣe tètè dé. Ẹ ṣeun.”

Lucy, Bridgend -England


Super-growth ṣiṣệ fún ệgbộn mi. Nί gbogbo ὶgbà èwe rè kὸ

bộwộ fún ararè ó sί máa ń r’ίrarệ lódὶlódὶ. Lệhὶn tó lo

Super-Growth fún bίi oṣù mệệfà ó ga nίwộn inches mệệta. Mo ti rί

ὶyίpadà fún rệrệ àtipé ὶgboyà re ti

yàtộ. A ṣiyèméjì nί àkộkộ bí a bá rò

iye owó re ṣùgbộn ótộsí láìníye. Mo jệ ọdún mệrindílógún mo sὶ nίrètί pé èmi náà ó rὶί èso

béè bí ó tilệjệpé ó jệ oréfé nίgbàmίràn. Mo nίgbàgbộ pé gίga sίi

le kàn ὶgboyà àti bί ènìà ṣe rί ayé.

– Marie

ọjộorí: 16

Australia

 

 

Ẹrί mί:

Láti àkókò tί mo ti fi sộkàn, mo kúrú ju àwọn ẹgbệ mi lọ. Mo

nírètí pé lộjộ kan màá ga dίè si tinú-tinú. Èyí ὸ

ṣẹlệ rárá, nítorínáà mo dán onírúurú èhù tó sọ pé mo le

ga sίi wò. Lệhὶn tί mo fowó sófo àtipé sùúrù mί titan. ộrémi

kan sộrộ nίpa “Super-Growth” fún mi. ὶgbà tó jệ wὶpé mi ὸ dábà, mo wὸyé

pé kὸle pamilára tί mo ba dánwὸ. Mo ra onί oṣù mệệfà, ὶyàlệnu ló sὶ jệ fún mi

pé óṣe bó ti sọ. Fún oṣù mệệta àkộkộ mo siyèméjὶ,

nίtorί ὶyίpadà dίè ni mo rί ṣùgbộn lệhὶn oṣù mệệfà, mo lọ láti 5’1 sί 5’31/2.

Obìnrin pệlú ọjộ ọkàndίnlógún ni mo jệ èhù yί sὶ yàmίlệnu. Ó

wùmί pé kίn ti dánwὸ kίn tó lo àwọn ti tệlệ, mi ó bá má ti fi

owó àti àkókó sófὸ.  Gbίyànjú k’ὶwọ náà dánwὸ!

Yasmin, USA

 

ṣé o t’irί ìrírí ànfàní èhù Super-Growth Height Enhancer? Bί o bá rί bệệ, fi ệrί rẹ ránsệ a ósὶ fún ọ nί èhù tί ὸń sộrộ nίpa lộfèé. Àń ṣàníyàn àti gbộ nίpa èso ìrírí re, ká fi ìyộrí-sí re han àwọn oníbàárà, onίsègùn ati aláìsàn yóókù. Fi fi ệrί rẹ ránsệ lórίi ίmèlὶ yί sales@super-growth.com

 

RA ỌJÀ

 

Ódáwalójú pé oó nítëêlôrùn pátápátá pệlú èhù ìyanu, èhù egbὸogi

Super-Growth Height Enhancer 

 ORDER

super-growth-order

Àń gba Western Union Money Transfer fún ìsanwó ọjà rίràláti orílè èdè mίràn. Tó bà nί ìbérè nίpa ọjà rίrà láti orílè èdè mίràn, fi ίmèlὶ ránṣệ sί : supergrowth@super-growth.com

 

Fún western union fast money transfer jộộ ίmèlὶ wa lóri:

sales@super-growth.com

 

Ộnà ìsanwó yί rọrùn àtipé ó gba-ye fún ìgbéṣẹ ὶfi ọjà ránṣệ nί kíákíá.

 

Gbogbo ibi tί ówà wo www.westernunion.com

 

Mo fi owó ránṣệ nίpa Western Union, óyajù ὶgbàwo ni màá rί ọjà gbà?

Gbogbo owó sίsan pệlú Western Union ńtệwálộwộ nίnu wákàtí mệrinlélógún. Á bệrệ ìgbéṣẹ báabá ti fẹsὶmúlệ.

 

CCNOW ni ńṣetὸ credit card wa. CCNOW jệ gệgệ bίi aláṣẹ fún àtútà ọjà wa. Credit card rẹ yó kọ CCNOW fún  àlàyé  ọjà rίrà rẹ. CCNOW yó pésè àwọn sávà tί yó fi àwọn ìwífún rẹ pamộ láìléwu. Àbὸ wà fún ọ. Kódà Super-Growth Inc. ónὶ àyè sί credit card re!

 

Àwọn credit card wo lè ńgbà?

 

CCNOW ńgbà Paypal, Visa, Mastercard, Discover/Novus, àti àwọn card American Express.  èyί kún àwọn kádὶ tó jệ èya Visa check cards àti debit cards, MasterCard “MasterMoney” card, etc.

 

 

Àmὶ ìdánilójú:

 

 • ὶgὸ kộkan Super-Growth © Formula ló kún fún eròjà tó lagbára gίga. Super-Growth Formula ṣẹ ệrί àìlábàwộn, titun àti ágbára.

 

 • Gbogbo ìwífún nίpa ὶrajà rẹ lá fipamộn á sί nί tàá tàbi fi sί ìwé àkójọ ίmèlὶ wa.

 

 • Gbogbo èhù la dί níṣọra, ṣétó àti fi ránṣệ nίnu ọjộ òwò kan.

 

 

Àwọn orílệ èdè tán ránjà sί (te àwòrán láti mú-tóbi)

Nίnu àkójọ ìsàlệ oórί àkójọ àwọn orílệ èdè tán ránjà sί.

 

 

PÈWÁ

 

Láti pèwá

Ộnà àti késί wa pộ nítorínáà má ṣàὶ fi ίmèlὶ, ệrọ ìbàniṣộrộ, fax tàbί fi ὶwé ránṣệ sί wa fún ìrànlộwộ. A wa làti ràn ộ lộwộ!

 

ĺmèlί (Email)

Fún ìbérè tó jọmộ èhù wa –

Bérè ìbérè supergrowth@super-growth.com

sales@super-growth.com

 

Ìbérè tó jộ mộ ipὸ ọjà re àti dίdá ọjà padà

(Mon- Thu 9 to 5 EST; Friday 9-4 EST)

service@super-growth.com

 

Fún ìbérè ὶsopộ: (ÀKίYÈSÍ: A ónὶ dáhùn tàbί ṣiṣệ lὸri  ìbérè ὶsopộ tóo bá fi ránṣệ sί ίmèlὶ mίràn)

links@super-growth.com

 

Fún ìbérè ti gbogbo –

service@super-growth.com

 

Tóbá jệpé gbộngan ìdárayá, ilé elégbògi tàbί oníbàárà òmíràn ni ó, o le rί ọjà wa rà nί ὶdίnwó fún àràtúntà.

 

lIé  /     ìwífún /      faq (ìbérè  ὶgbàgbogbo)    / àwọn ệrί /    rajà /     pèwá/    

Leave a Reply

Your email address will not be published.